Daniẹli 7:3 - Bibeli Mimọ3 Ẹranko mẹrin nla si ti inu okun jade soke, nwọn si yatọ si ara wọn. Faic an caibideilYoruba Bible3 Àwọn ẹranko ńláńlá mẹrin bá jáde láti inú òkun. Ọ̀kan kò jọ̀kan ni àwọn mẹrẹẹrin. Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní3 Ẹranko ńlá mẹ́rin tí ó yàtọ̀ sí ara wọn, jáde láti inú Òkun náà. Faic an caibideil |