Daniẹli 4:10 - Bibeli Mimọ10 Bayi ni iran ori mi lori akete mi; mo ri, si kiyesi i, igi kan duro li arin aiye, giga rẹ̀ si pọ̀ gidigidi. Faic an caibideilYoruba Bible10 “Nígbà tí mo sùn, mo rí igi kan láàrin ayé, lójú ìran, igi náà ga lọpọlọpọ. Faic an caibideilBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní10 Èyí ni ìran náà tí mo rí nígbà tí mo wà lórí ibùsùn mi, mo rí igi kan láàrín ayé, igi náà ga gidigidi. Faic an caibideil |