Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -




1 Peteru 2:3 - Bibeli Mimọ

3 Bi ẹnyin ba ti tọ́ ọ wò pe, olõre li Oluwa:

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Yoruba Bible

3 Ó ṣá ti hàn si yín pé olóore ni Oluwa.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

3 nísinsin yìí tí ẹ̀yin ti tọ́ ọ wò pé rere ni Olúwa.

Faic an caibideil Dèan lethbhreac




1 Peteru 2:3
8 Iomraidhean Croise  

Tali Ọba ogo yi? Oluwa ti o le, ti o si lagbara, Oluwa ti o lagbara li ogun.


Tọ́ ọ wò, ki o si ri pe, rere ni Oluwa: alabukún fun li ọkunrin na ti o gbẹkẹle e.


Bi ẹnipe ijà ati ọ̀ra bẹ̃ni yio tẹ ọkàn mi lọrun; ẹnu mi yio si ma fi ète ayọ̀ yìn ọ:


Awọn ti o si mọ̀ orukọ rẹ o gbẹkẹ le ọ: nitori iwọ, Oluwa, kò ti ikọ̀ awọn ti nṣe afẹri rẹ silẹ.


Bi igi eleso lãrin awọn igi igbẹ, bẹ̃li olufẹ mi ri lãrin awọn ọmọkunrin. Emi fi ayọ̀ nla joko labẹ ojiji rẹ̀, eso rẹ̀ si dùn mọ mi li ẹnu.


Nitori ore rẹ̀ ti tobi to, ẹwà rẹ̀ si ti pọ̀ to! ọkà yio mu ọdọmọkunrin darayá, ati ọti-waini titún yio mu awọn ọdọmọbinrin ṣe bẹ̃ pẹlu.


Ṣugbọn nigbati ìṣeun Ọlọrun Olugbala wa ati ifẹ rẹ̀ si enia farahan,


Lean sinn:

Sanasan


Sanasan