Biblia Todo Logo
Bìoball air-loidhne

- Sanasan -

O. Daf 134 - Bibeli Mimọ


Ẹ yin OLUWA

1 Ẹ kiyesi i, ẹ fi ibukún fun Oluwa, gbogbo ẹnyin iranṣẹ Oluwa, ti nduro ni ile Oluwa li oru.

2 Ẹ gbé ọwọ nyin soke si ibi-mimọ́, ki ẹ si fi ibukún fun Oluwa.

3 Oluwa ti o da ọrun on aiye, ki o busi i fun ọ lati Sioni wá.

Yoruba Bible Crowther Version © The Bible Society of Nigeria, 2012.

Bible Society of Nigeria
Lean sinn:



Sanasan