Numeri 7:6 - Yoruba Bible6 Mose bá gba àwọn ọkọ̀ ẹrù ati àwọn akọ mààlúù náà, ó kó wọn fún àwọn ọmọ Lefi. See the chapterBibeli Mimọ6 Mose si gbà kẹkẹ́-ẹrù wọnni, ati akọmalu, o si fi wọn fun awọn ọmọ Lefi. See the chapterBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní6 Mose sì kó àwọn kẹ̀kẹ́ ẹrù àti akọ màlúù náà fún àwọn ọmọ Lefi. See the chapter |