Numeri 3:49 - Yoruba Bible49 Mose gba owó ìràpadà náà lórí àwọn tí iye àkọ́bí àwọn ọmọ Israẹli fi pọ̀ ju àwọn ọmọ Lefi lọ. See the chapterBibeli Mimọ49 Mose si gbà owo ìrapada lọwọ awọn ti o lé lori awọn ti a fi awọn ọmọ Lefi rasilẹ: See the chapterBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní49 Nígbà náà ni Mose gba owó ìràpadà àwọn ènìyàn tó ṣẹ́kù lẹ́yìn tí àwọn ọmọ Lefi ti ra àwọn yòókù padà. See the chapter |