Numeri 3:48 - Yoruba Bible48 Kí o sì kó owó náà fún Aaroni ati àwọn ọmọ rẹ̀.” See the chapterBibeli Mimọ48 Ki o si fi ninu owo na, ani owo ìrapada ti o lé ninu wọn, fun Aaroni ati fun awọn ọmọ rẹ̀. See the chapterBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní48 Owó tí a fi ra àwọn àkọ́bí ọmọ Israẹli tó lé yìí, ni kí o kó fún Aaroni àti àwọn ọmọ rẹ̀. See the chapter |