Numeri 3:24 - Yoruba Bible24 Eliasafu ọmọ Laeli ni yóo jẹ́ olórí wọn. See the chapterBibeli Mimọ24 Ati Eliasafu ọmọ Laeli ni ki o ṣe olori ile baba awọn ọmọ Gerṣoni. See the chapterBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní24 Olórí àwọn ìdílé Gerṣoni ni Eliasafu ọmọ Láélì. See the chapter |