Numeri 2:30 - Yoruba Bible30 Àwọn ọmọ ogun rẹ̀ tí a kà jẹ́ ọ̀kẹ́ meji ó lé ẹẹdẹgbaaje ati irinwo (53,400). See the chapterBibeli Mimọ30 Ati ogun rẹ̀, ati awọn ti a kà ninu wọn, jẹ́ ẹgba mẹrindilọgbọ̀n o le egbeje. See the chapterBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní30 Iye ìpín rẹ̀ jẹ́ ẹgbàá-mẹ́rìn-dínlógún ó-lé-egbèje (53,400). See the chapter |