Numeri 2:29 - Yoruba Bible29 Lẹ́yìn náà ni ẹ̀yà Nafutali; Ahira, ọmọ Enani ni yóo jẹ́ olórí wọn. See the chapterBibeli Mimọ29 Ati ẹ̀ya Naftali: Ahira ọmọ Enani yio si jẹ́ olori awọn ọmọ Naftali: See the chapterBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní29 Ẹ̀yà Naftali ni yóò kàn lẹ́yìn wọn. Olórí Naftali ni Ahira ọmọ Enani. See the chapter |