Numeri 1:29 - Yoruba Bible29 jẹ́ ẹgbaa mẹtadinlọgbọn ó lé irinwo (54,400). See the chapterBibeli Mimọ29 Awọn ti a kà ninu wọn, ninu ẹ̀ya Issakari, o jẹ́ ẹgbã mẹtadilọgbọ̀n o le irinwo. See the chapterBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní29 Iye tí a kà nínú ẹ̀yà Isakari jẹ́ ẹgbàá-mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n ó-lé-irínwó (54,400). See the chapter |