Online Bible

- Advertisements -




Matiu 2:4 - Yoruba Bible

4 Ọba bá pe gbogbo àwọn olórí alufaa ati àwọn amòfin láàrin àwọn eniyan, ó wádìí nípa ibi tí a óo ti bí Kristi lọ́wọ́ wọn.

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

4 Nigbati o si pè gbogbo awọn olori alufa ati awọn akọwe awọn enia jọ, o bi wọn lẽre ibiti a o gbé bí Kristi.

See the chapter Copy

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

4 Nígbà tí ó sì pe àwọn olórí àlùfáà àti àwọn olùkọ́ òfin jọ, ó bi wọ́n léèrè níbi ti a ó gbé bí Kristi?

See the chapter Copy




Matiu 2:4

Follow us:

Advertisements


Advertisements