Online Bible

- Advertisements -




Matiu 2:2 - Yoruba Bible

2 Wọ́n bèèrè pé, “Níbo ni ọmọ tí a bí tí yóo jẹ ọba àwọn Juu wà? A ti rí ìràwọ̀ rẹ̀ ní ìlà oòrùn, nítorí náà ni a ṣe wá láti júbà rẹ̀.”

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

2 Nwọn mbère wipe, Nibo li ẹniti a bí ti iṣe ọba awọn Ju wà? nitori awa ti ri irawọ rẹ̀ ni ìla-õrùn, awa si wá lati foribalẹ fun u.

See the chapter Copy

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

2 Wọ́n si béèrè pé, “Níbo ni ẹni náà tí a bí tí í ṣe ọba àwọn Júù wà? Àwa ti rí ìràwọ̀ rẹ̀ ní ìlà-oòrùn, a sì wá láti foríbalẹ̀ fún un.”

See the chapter Copy




Matiu 2:2

Follow us:

Advertisements


Advertisements