Marku 5:6 - Yoruba Bible6 Ṣugbọn nígbà tí ó rí Jesu lókèèrè, ó sáré, ó dọ̀bálẹ̀ níwájú rẹ̀. See the chapterBibeli Mimọ6 Ṣugbọn nigbati o ri Jesu li òkere, o sare wá, o si foribalẹ fun u, See the chapterBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní6 Nígbà tí ó sì rí Jesu látòkèrè, ó sì sáré lọ láti pàdé rẹ̀. Ó sì wólẹ̀ níwájú rẹ̀. See the chapter |