Online Bible

- Advertisements -




Marku 2:25 - Yoruba Bible

25 Jesu dá wọn lóhùn pé, “Ẹ kò ì tíì ka ohun tí Dafidi ṣe, nígbà tí kò ní oúnjẹ, tí ebi ń pa òun ati àwọn tí ó wà pẹlu rẹ̀?

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

25 O si wi fun wọn pe, Ẹnyin kò ti kà ohun ti Dafidi ṣe, nigbati o ṣe alaini, ti ebi si npa a, on, ati awọn ti o wà lọdọ rẹ̀?

See the chapter Copy

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

25 Ó dá wọn lóhùn pé, “Ẹ̀yin kò ti ka ohun tí Dafidi ṣe, nígbà tí ó ṣe aláìní, tí ebi sì ń pa á, òun àti àwọn tí ó wà lọ́dọ̀ rẹ̀?

See the chapter Copy




Marku 2:25

Follow us:

Advertisements


Advertisements