Joẹli 3:20 - Yoruba Bible20 Ṣugbọn àwọn eniyan yóo máa gbé ilẹ̀ Juda títí lae, wọn óo sì máa gbé ìlú Jerusalẹmu láti ìrandíran. See the chapterBibeli Mimọ20 Ṣugbọn Juda yio joko titi lai, ati Jerusalemu lati iran de iran. See the chapterBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní20 Ṣùgbọ́n Juda yóò jẹ́ ibùgbé títí láé, àti Jerusalẹmu láti ìran dé ìran. See the chapter |