Joẹli 2:6 - Yoruba Bible6 Ìdààmú bá àwọn orílẹ̀-èdè tí ó bá ti fojú kàn wọ́n, gbogbo ọkàn á rẹ̀wẹ̀sì. See the chapterBibeli Mimọ6 Li oju wọn, awọn enia yio jẹ irora pupọ̀: gbogbo oju ni yio ṣú dùdu. See the chapterBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní6 Ní ojú wọn, àwọn ènìyàn yóò jẹ ìrora púpọ̀: gbogbo ojú ní yóò ṣú dudu. See the chapter |