Joẹli 2:22 - Yoruba Bible22 Ẹ má bẹ̀rù, ẹ̀yin ẹranko inú igbó, nítorí ewéko gbogbo ni ó tutù, igi gbogbo ti so èso, igi ọ̀pọ̀tọ́ ati ọgbà àjàrà sì ti so jìnwìnnì. See the chapterBibeli Mimọ22 Ẹ má bẹ̀ru, ẹranko igbẹ: nitori pápa-oko aginju nrú, nitori igi nso eso rẹ̀, igi ọ̀pọtọ ati àjara nso eso ipá wọn. See the chapterBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní22 Ẹ má bẹ̀rù, ẹranko igbó, nítorí pápá oko aginjù ń rú, nítorí igi ń so èso rẹ̀, igi ọ̀pọ̀tọ́ àti àjàrà ń so èso ọ̀rọ̀ wọn. See the chapter |