Online Bible

- Advertisements -




Joẹli 2:19 - Yoruba Bible

19 OLUWA dá àwọn eniyan rẹ̀ lóhùn pé, “Wò ó! N óo fun yín ní ọkà, waini ati òróró, ẹ óo ní ànítẹ́rùn. N kò ní sọ yín di ẹni ẹ̀gàn láàrin àwọn orílẹ̀-èdè yòókù mọ́.

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

19 Nitõtọ, Oluwa yio dahùn, yio si wi fun awọn enia rẹ̀ pe, Wò o emi o rán ọkà, ati ọti-waini, ati ororo si nyin, a o si fi wọn tẹ́ nyin lọrùn: emi kì yio si fi nyin ṣe ẹ̀gan mọ lãrin awọn keferi.

See the chapter Copy

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

19 Nítòótọ́, Olúwa yóò dá wọn lóhùn: “Yóò sì wí fun àwọn ènìyàn rẹ̀ pé, Wò ó èmi yóò rán ọkà, àti ọtí wáìnì tuntun, àti òróró sí i yín, a ó sì fi wọn tẹ́ yín lọ́rùn: èmi kì yóò sì fi yín ṣe ẹ̀gàn mọ́ láàrín àwọn aláìkọlà.

See the chapter Copy




Joẹli 2:19

Follow us:

Advertisements


Advertisements