Joẹli 2:18 - Yoruba Bible18 Nígbà náà ni ara bẹ̀rẹ̀ sí ta OLUWA nítorí ilẹ̀ rẹ̀, ó sì ṣàánú fún àwọn eniyan rẹ̀. See the chapterBibeli Mimọ18 Nigbana ni Oluwa yio jowú fun ilẹ rẹ̀, yio si kãnu fun enia rẹ̀. See the chapterBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní18 Nígbà náà ní Olúwa yóò jowú fún ilẹ̀ rẹ̀, yóò sì káàánú fún ènìyàn rẹ̀. See the chapter |