Online Bible

- Advertisements -




Esteri 3:11 - Yoruba Bible

11 Ọba sọ fún un pé, “Má wulẹ̀ san owó kankan, àwọn eniyan náà wà ní ìkáwọ́ rẹ, lọ ṣe wọ́n bí o bá ti fẹ́.”

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

11 Ọba si wi fun Hamani pe, a fi fadaka na bùn ọ, ati awọn enia na pẹlu, lati fi wọn ṣe bi o ti dara loju rẹ.

See the chapter Copy

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

11 Ọba sọ fún Hamani pé, “pa owó náà mọ́, kí o sì ṣe ohun tí ó wù ọ́ fún àwọn ènìyàn náà.”

See the chapter Copy




Esteri 3:11

Follow us:

Advertisements


Advertisements