Online Bible

- Advertisements -




Esteri 2:6 - Yoruba Bible

6 Ó wà lára àwọn tí Nebukadinesari ọba Babiloni kó lẹ́rú láti Jerusalẹmu lọ sí ilẹ̀ Babiloni pẹlu Jekonaya, ọba Juda.

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

6 Ẹniti a ti mu lọ lati Jerusalemu pẹlu ìgbekun ti a kó lọ pẹlu Jekoniah, ọba Juda, ti Nebukadnessari, ọba Babeli ti kó lọ.

See the chapter Copy

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

6 Ẹni tí Nebukadnessari ọba Babeli ti gbé lọ sí ìgbèkùn láti Jerusalẹmu, lára àwọn tí wọ́n kó ní ìgbèkùn pẹ̀lú ọba Jekoniah ọba Juda.

See the chapter Copy




Esteri 2:6

Follow us:

Advertisements


Advertisements