Eksodu 2:25 - Yoruba Bible25 Ọlọrun bojú wo àwọn eniyan Israẹli, ó sì rí irú ipò tí wọ́n wà. See the chapterBibeli Mimọ25 Ọlọrun si bojuwò awọn ọmọ Israeli, Ọlọrun si mọ̀ ọ fun wọn. See the chapterBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní25 Nítorí náà, Ọlọ́run bojú wo àwọn ará Israẹli, Ó sì wà láti gbà wọ́n sílẹ̀. See the chapter |