Eksodu 1:13 - Yoruba Bible13 Nítorí náà, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí fi iṣẹ́ àṣekára ni àwọn ọmọ Israẹli lára, See the chapterBibeli Mimọ13 Awọn ara Egipti si mu awọn ọmọ Israeli sìn li asìnpa: See the chapterBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní13 Àwọn ará Ejibiti sì mú àwọn ọmọ Israẹli sìn ní àsìnpa. See the chapter |