Online Bible

- Advertisements -




Efesu 2:20 - Yoruba Bible

20 Lórí àwọn aposteli ati àwọn wolii ni a ti fi ìpìlẹ̀ ìdílé yìí lélẹ̀, Kristi Jesu fúnrarẹ̀ sì ni òkúta igun ilé.

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

20 A si ngbé nyin ró lori ipilẹ awọn aposteli, ati awọn woli, Jesu Kristi tikararẹ̀ jẹ pàtaki okuta igun ile;

See the chapter Copy

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

20 a sì ń gbé yín ró lórí ìpìlẹ̀ àwọn aposteli, àti àwọn wòlíì, pẹ̀lú Jesu Kristi fúnrarẹ̀ gẹ́gẹ́ bí pàtàkì òkúta igun ilé;

See the chapter Copy




Efesu 2:20

Follow us:

Advertisements


Advertisements