Daniẹli 6:9 - Yoruba Bible9 Nítorí náà, Dariusi ọba fi ọwọ́ sí òfin náà, ó sì fi òǹtẹ̀ tẹ̀ ẹ́. See the chapterBibeli Mimọ9 Nigbana ni Dariusi fi ọwọ sinu iwe ati aṣẹ na. See the chapterBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní9 Nígbà náà, ni Dariusi ọba fi ọwọ́ sí ìwé àṣẹ náà. See the chapter |