Daniẹli 5:30 - Yoruba Bible30 Ní alẹ́ ọjọ́ náà gan-an ni wọ́n pa Beṣasari, ọba àwọn ará Kalidea. See the chapterBibeli Mimọ30 Loru ijọ kanna li a pa Belṣassari, ọba awọn ara Kaldea. See the chapterBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní30 Ní alẹ́ ọjọ́ náà ni a pa Belṣassari, ọba àwọn ara Kaldea. See the chapter |