Online Bible

- Advertisements -




Daniẹli 4:1 - Yoruba Bible

1 Ọba Babiloni ranṣẹ sí gbogbo àwọn eniyan, ati gbogbo orílẹ̀-èdè ati ẹ̀yà ní gbogbo ayé, pé: “Kí alaafia wà pẹlu yín!

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

1 NEBUKADNESSARI ọba, si gbogbo enia, orilẹ, ati ède, ti o ngbe gbogbo agbaiye; ki alafia ki o ma pọ̀ si i fun nyin.

See the chapter Copy

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

1 Nebukadnessari ọba, Sí gbogbo ènìyàn, orílẹ̀ àti onírúurú èdè, tí ó ń gbé ní àgbáyé: Kí àlàáfíà máa pọ̀ sí i fún un yín. Kí ẹ ṣe rere tó pọ̀!

See the chapter Copy




Daniẹli 4:1

Follow us:

Advertisements


Advertisements