Numeri 4:38 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní38 Wọ́n ka àwọn ọmọ Gerṣoni nípa ìdílé àti ilé baba wọn. See the chapterYoruba Bible38 Iye àwọn ọmọ Geriṣoni ní ìdílé-ìdílé, gẹ́gẹ́ bí ilé baba wọn, See the chapterBibeli Mimọ38 Awọn ti a si kà ninu awọn ọmọ Gerṣoni, nipa idile wọn, ati gẹgẹ bi ile baba wọn, See the chapter |