Numeri 4:36 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní36 Iye wọn nípa ìdílé jẹ́ ẹgbẹ̀rìnlá ó-dínàádọ́ta (2,750). See the chapterYoruba Bible36 Iye wọ́n jẹ́ ẹgbẹrinla ó dín aadọta (2,750). See the chapterBibeli Mimọ36 Awọn ti a si kà ninu wọn nipa idile wọn jẹ́ ẹgbẹrinla o din ãdọta. See the chapter |