Numeri 4:24 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní24 “Èyí ni iṣẹ́ ìsìn ìdílé àwọn ọmọ Gerṣoni, bí wọ́n ti ń ṣiṣẹ́ àti ní ẹrù rírù: See the chapterYoruba Bible24 Iṣẹ́ ìsìn ti àwọn ọmọ Geriṣoni nìyí: See the chapterBibeli Mimọ24 Eyi ni iṣẹ-ìsin idile awọn ọmọ Gerṣoni, lati sìn ati lati rù ẹrù: See the chapter |