Numeri 3:30 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní30 Olórí àwọn ìdílé Kohati ni Elisafani ọmọ Usieli. See the chapterYoruba Bible30 Elisafani ọmọ Usieli ni yóo jẹ́ olórí wọn. See the chapterBibeli Mimọ30 Ati Elisafani ọmọ Usieli ni ki o ṣe olori ile baba awọn idile awọn ọmọ Kohati. See the chapter |