Online Bible

- Advertisements -




Numeri 2:33 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

33 Ṣùgbọ́n a kò ka àwọn ọmọ Lefi papọ̀ mọ́ àwọn Israẹli gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pa á láṣẹ fún Mose.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

33 Ṣugbọn a kò ka àwọn ẹ̀yà Lefi mọ́ àwọn ọmọ Israẹli, gẹ́gẹ́ bí àṣẹ tí OLUWA pa fún Mose.

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

33 Ṣugbọn awọn ọmọ Lefi li a kò kà mọ́ awọn ọmọ Israeli; bi OLUWA ti paṣẹ fun Mose.

See the chapter Copy




Numeri 2:33

Follow us:

Advertisements


Advertisements