Online Bible

- Advertisements -




Numeri 2:21 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

21 Iye ìpín rẹ̀ ni ẹgbàá-mẹ́rìn-dínlógún ó-lé-igba (32,200).

See the chapter Copy

Yoruba Bible

21 Àwọn ọmọ ogun rẹ̀ tí a kà jẹ́ ọ̀kẹ́ kan ó lé ẹgbaafa ó lé igba (32,200).

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

21 Ati ogun rẹ̀, ati awọn ti a kà ninu wọn, jẹ́ ẹgba mẹrindilogun o le igba.

See the chapter Copy




Numeri 2:21

Follow us:

Advertisements


Advertisements