Online Bible

- Advertisements -




Matiu 2:5 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

5 Wọ́n sì wí pé, “Ní Bẹtilẹhẹmu ti Judea, èyí ni ohun tí wòlíì ti kọ ìwé rẹ̀ pé:

See the chapter Copy

Yoruba Bible

5 Wọ́n sọ fún un pé, “Ní Bẹtilẹhẹmu ti ilẹ̀ Judia ni. Nítorí bẹ́ẹ̀ ni ó wà ní àkọsílẹ̀ wolii nì pé.

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

5 Nwọn si wi fun u pe, Ni Betlehemu ti Judea ni: nitori bẹ̃li a kọwe rẹ̀ lati ọwọ́ woli nì wá,

See the chapter Copy




Matiu 2:5

Follow us:

Advertisements


Advertisements