Online Bible

- Advertisements -




Marku 7:20 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

20 Nígbà náà, ó fi kún un pé: “Èyí ti ó ti ọkàn ènìyàn jáde ni ń sọ ni di aláìmọ́.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

20 Ó tún fi kún un pé, “Àwọn nǹkan tí ń jáde láti inú eniyan ni ó ń sọ ọ́ di aláìmọ́.

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

20 O si wipe, Eyi ti o ti inu enia jade, eyini ni isọ enia di alaimọ́.

See the chapter Copy




Marku 7:20

Follow us:

Advertisements


Advertisements