Online Bible

- Advertisements -




Marku 6:50 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

50 nítorí gbogbo wọn ni ó rí i, tí ẹ̀rù sì bà wọ́n. Ṣùgbọ́n òun sọ̀rọ̀ sí wọn lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ pé, “Ẹ mú ọkàn le! Èmi ni. Ẹ má bẹ̀rù.”

See the chapter Copy

Yoruba Bible

50 Nítorí gbogbo wọn ni wọ́n rí i tí ẹ̀rù sì bà wọ́n. Ṣugbọn lójú kan náà ó fọhùn sí wọn, ó ní, “Ẹ fi ọkàn balẹ̀. Èmi ni. Ẹ má bẹ̀rù.”

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

50 Nitori gbogbo wọn li o ri i, ti ẹ̀ru si ba wọn. Ṣugbọn lojukanna o si ba wọn sọ̀rọ, o si wi fun wọn pe, Ẹ tújuka: Emi ni; ẹ má bẹ̀ru.

See the chapter Copy




Marku 6:50

Follow us:

Advertisements


Advertisements