Online Bible

- Advertisements -




Marku 6:47 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

47 Nígbà tí ó di alẹ́, ọkọ̀ wà láàrín Òkun, òun nìkan sì wà lórí ilẹ̀.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

47 Nígbà tí ilẹ̀ ṣú, àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ wà ninu ọkọ̀ ní ààrin òkun, òun nìkan ni ó kù lórí ilẹ̀.

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

47 Nigbati alẹ si lẹ, ọkọ̀ si wà larin okun, on nikan si wà ni ilẹ.

See the chapter Copy




Marku 6:47

Follow us:

Advertisements


Advertisements