Online Bible

- Advertisements -




Marku 6:43 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

43 Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn sì kó agbọ̀n méjìlá tí ó kún fún àjẹkù àkàrà àti ti ẹja pẹ̀lú.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

43 Wọ́n bá kó àjẹkù burẹdi ati ẹja jọ, ó kún agbọ̀n mejila.

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

43 Nwọn si kó agbọ̀n mejila kún fun ajẹkù, ati ti ẹja pẹlu.

See the chapter Copy




Marku 6:43

Follow us:

Advertisements


Advertisements