Online Bible

- Advertisements -




Marku 6:32 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

32 Nítorí náà, wọ́n wọ ọkọ̀ ojú omi kúrò níbẹ̀ lọ sí ibi tí ó parọ́rọ́.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

32 Wọ́n bá bọ́ sinu ọkọ̀ ojú omi kan, wọ́n fẹ́ yọ́ lọ sí ibi tí kò sí eniyan.

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

32 Nwọn si ba ti ọkọ̀ lọ si ibi ijù awọn nikan.

See the chapter Copy




Marku 6:32

Follow us:

Advertisements


Advertisements