Online Bible

- Advertisements -




Marku 6:30 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

30 Àwọn aposteli kó ara wọn jọ sí ọ̀dọ̀ Jesu, wọ́n sí ròyìn ohun gbogbo tí wọ́n ti ṣe àti ohun gbogbo tí wọ́n ti kọ́ni.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

30 Àwọn aposteli Jesu pé jọ sí ọ̀dọ̀ rẹ̀, wọ́n ròyìn gbogbo nǹkan tí wọ́n ti ṣe ati bí wọ́n ti kọ́ àwọn eniyan.

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

30 Awọn aposteli si kó ara wọn jọ sọdọ Jesu, nwọn si ròhin ohungbogbo ti nwọn ti ṣe fun u, ati ohungbogbo ti nwọn ti kọni.

See the chapter Copy




Marku 6:30

Follow us:

Advertisements


Advertisements