Online Bible

- Advertisements -




Marku 6:19 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

19 Nítorí náà ni Herodia ṣe ní sínú, òun sì fẹ́ pa á, ṣùgbọ́n kò le ṣe é.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

19 Nítorí náà Hẹrọdiasi ní Johanu sinu, ó fẹ́ pa á, ṣugbọn kò lè pa á,

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

19 Nitorina ni Herodia ṣe ni i sinu, on si nfẹ ipa a; ṣugbọn kò le ṣe e:

See the chapter Copy




Marku 6:19

Follow us:

Advertisements


Advertisements