Online Bible

- Advertisements -




Marku 6:17 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

17 Herodu fúnrarẹ̀ sá ti ránṣẹ́ mú Johanu, tìkára rẹ̀ sínú túbú nítorí Herodia aya Filipi arákùnrin rẹ̀ nítorí tí ó fi ṣe aya.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

17 Nítorí Hẹrọdu kan náà yìí ni ó ranṣẹ lọ mú Johanu tí ó fi í sẹ́wọ̀n nítorí ọ̀ràn Hẹrọdiasi iyawo Filipi arakunrin Hẹrọdu tí Hẹrọdu gbà.

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

17 Herodu tikararẹ̀ sá ti ranṣẹ mu Johanu, o si dè e sinu tubu nitori Herodia, aya Filippi arakunrin rẹ̀: on sá ti fi i ṣe aya.

See the chapter Copy




Marku 6:17

Follow us:

Advertisements


Advertisements