Online Bible

- Advertisements -




Marku 6:15 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

15 Àwọn mìíràn wí pé, “Elijah ní.” Àwọn mìíràn wí pé, “Wòlíì bí ọ̀kan lára àwọn àtijọ́ tó ti kú ló tún padà sáyé.”

See the chapter Copy

Yoruba Bible

15 Ṣugbọn àwọn mìíràn ń wí pé, “Elija ni.” Àwọnmìíràn ní, “Wolii ni, bí ọ̀kan ninu àwọn wolii àtijọ́.”

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

15 Awọn ẹlomiran wipe, Elijah ni. Ṣugbọn awọn miran wipe, Woli kan ni, tabi bi ọkan ninu awọn woli.

See the chapter Copy




Marku 6:15

Follow us:

Advertisements


Advertisements