Online Bible

- Advertisements -




Marku 6:12 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

12 Wọ́n jáde lọ láti wàásù ìrònúpìwàdà fún àwọn ènìyàn.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

12 Bí àwọn ọmọ-ẹ̀yìn mejila ti ń lọ, wọ́n ń waasu pé kí gbogbo eniyan ronupiwada.

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

12 Nwọn si jade lọ, nwọn si wasu ki awọn enia ki o le ronupiwada.

See the chapter Copy




Marku 6:12

Follow us:

Advertisements


Advertisements