Online Bible

- Advertisements -




Marku 6:10 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

10 Jesu wí pé, “Ẹ dúró sí ilé kan ní ìletò kan. Ẹ má ṣe sípò padà láti ilé dé ilé, nígbà tí ẹ bá wà ní ìlú náà.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

10 Ó tún fi kún un fún wọn pé, “Ilékílé tí ẹ bá wọ̀, níbẹ̀ ni kí ẹ máa gbé títí ẹ óo fi kúrò ní ìlú náà.

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

10 O si wi fun wọn pe, Nibikibi ti ẹnyin ba wọ̀ ile kan, nibẹ̀ ni ki ẹ mã gbé titi ẹnyin o fi jade kuro nibẹ̀ na.

See the chapter Copy




Marku 6:10

Follow us:

Advertisements


Advertisements