Marku 5:32 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní32 Síbẹ̀, Jesu bẹ̀rẹ̀ sí wò yíká láti rí ẹni náà, tí ó fi ọwọ́ kan òun. See the chapterYoruba Bible32 Ṣugbọn Jesu ń wò yíká láti rí ẹni tí ó fọwọ́ kan aṣọ rẹ̀. See the chapterBibeli Mimọ32 O si wò yiká lati ri ẹniti o ṣe nkan yi. See the chapter |