Online Bible

- Advertisements -




Marku 5:27 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

27 Nígbà tí ó sì gbúròó iṣẹ́ ìyanu tí Jesu ṣe, ìdí nìyìí tí ó fi wá sẹ́yìn rẹ̀, láàrín ọ̀pọ̀ ènìyàn, ó sì fọwọ́ kan aṣọ rẹ̀.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

27 Nígbà tí obinrin náà gbọ́ nípa Jesu, ó gba ààrin àwọn eniyan dé ẹ̀yìn rẹ̀, ó bá fi ọwọ́ kan aṣọ rẹ̀,

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

27 Nigbati o gburo Jesu, o wá sẹhin rẹ̀ larin ọ̀pọ enia, o fọwọ́kàn aṣọ rẹ̀.

See the chapter Copy




Marku 5:27

Follow us:

Advertisements


Advertisements