Online Bible

- Advertisements -




Marku 5:10 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

10 Nígbà náà ni ẹ̀mí àìmọ́ náà bẹ̀rẹ̀ sí í bẹ Jesu gidigidi, kí ó má ṣe rán àwọn jáde kúrò ní agbègbè náà.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

10 Ó bá bẹ̀rẹ̀ sí bẹ Jesu títí pé kí ó má ṣe lé wọn jáde kúrò ní agbègbè ibẹ̀.

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

10 O si bẹ̀ ẹ gidigidi pe, ki o máṣe rán wọn jade kuro ni ilẹ na.

See the chapter Copy




Marku 5:10

Follow us:

Advertisements


Advertisements