Marku 3:33 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní33 Ṣùgbọ́n ó dá wọn lóhùn wí pé, “Ta ni í ṣe ìyá mi tàbí àwọn arákùnrin mi?” See the chapterYoruba Bible33 Ó dá wọn lóhùn pé, “Ta ni ìyá mi ati arakunrin mi?” See the chapterBibeli Mimọ33 O si da wọn lohùn, wipe, Tani iṣe iya mi, tabi awọn arakunrin mi? See the chapter |